Добавил:
Upload Опубликованный материал нарушает ваши авторские права? Сообщите нам.
Вуз: Предмет: Файл:

YorubaPrimer

.pdf
Скачиваний:
6
Добавлен:
12.02.2015
Размер:
4.28 Mб
Скачать

Àkójôpõ õrõ létò çlëgbëmçgbë Vocabulary - in functional groups

Àárõ

à-á-

morning

 

Àríwá

à--

north

Õsán

õ-sán

afternoon

 

Gúúsù

-ú-

south

Ìrõlë

ì--

late

 

Ìlà-oòrùn

ì--o-ò-rùn

east

Alë

a-

afternoon

 

Ìwõ-oòrùn

ì--o-o-rùn

west

Òru

ò-ru

evening

 

 

 

 

 

 

(after dark)

 

Àwõ

à-

color

Àkókò

à--

night

 

Pupa

pu-pa

red

Ìÿëjú

ì--

 

 

Funfun

fun-fun

white

Wákàtí

--

time

 

Dúdú

-

black, dark

Ôjö

o-

minute

 

 

 

 

Õsê

õ-

hour

 

Ilé

i-

house

Oÿù

o-ÿù

day

 

Yàrá

-

room

Ôdún

ô-dún

week

 

Õdêdê

õ--

porch, lobby

 

 

month

 

Ìyêwù

ì--

hall

Àná

à-

year

 

Gbàngàn

gbàn-gàn

bedroom

Òní (Èní)

ò-(è-)

 

 

Balùwê

ba--

bathroom

Õla

õ-la

yesterday

 

Ilêkùn

i--kùn

door

Õtúnla

õ-tún-la

today

 

Fèrèsé

--

window

Ìjçta

ì--ta

tomorrow

 

Ògiri

ò-gi-ri

wall

Ìjçrin

ì--rin

two days

 

Àjà

à-

attic

Ìjarùn-ún

ì-ja-rùn-ún

ago

 

 

 

 

 

 

three days

 

ßíbí

ÿí-

spoon

Õsê tó kôjá

õ-

ago

 

Õbç

õ-

knife

Õsê tó þ bõ

-

four days

 

Àmúga

à--ga

fork

 

õ-tó þ

ago

 

Àwo

à-wo

porcelain

 

last week

 

 

 

bowl, plate

 

 

next week

 

Abö

a-

enamel or

Oòrùn

o-ò- rùn

 

 

 

 

plastic bowl

Òÿùpá

ò-ÿù-

sun

 

 

 

pan

Ìràwõ

ì--

moon

 

Ife

i-fe

cup, tumbler

Òfúrufú

ò--ru-

star

 

Ìkòkò

ì--

pot

Ayé

a-

sky

 

 

 

 

Õrun

õ-run

earth

 

Akëkõö

a---ö

student/pupil

Òjò

ò-

heaven

 

Olùkö

o--

teacher

 

 

rain

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

(Five short of seventy)

Page 65

Ojú Ìwé Karùndínláàádörin

Àkójôpõ õrõ létò çlëgbëmçgbë

Vocabulary - in functional groups

Ebi

e-bi

hunger

Bàbá

Òýgbç

ò-ý-gbç

thirst

Ìyá

Oúnjç

o-ún-

food

Õgbçni

Omi

o-mi

water

Ìyá-ààfin

Ôbê

ô-

stew

Abilékô

Çran

-ran

meat

Omidan

Çja

ç-ja

fish

Adélébõ

Aÿô

a-ÿô

cloth,garment

Gbóná

Fìlà

-

cap

Tútù

ßõkòtò

ÿò--

trousers, shorts

Löwörö

Bùbá

-

tunic, blouse

 

Ìró

ì-

loin cloth

Onílé

Gèlè

-

head-tie

Àlejò

Bàtà

-

shoe

Õgá

Ìbõsê

ì--

socks

Ômô-iÿë

Pátá

-

panties

Ômô-õdõ

ßinmí

ÿin-

undergarment,

 

 

 

chemise

Ìbéèrè

 

 

 

Ìdáhùn

Arúgbó

a--gbó

elderly person

Èsì

Àgbà

à-gbà

elder

Òkè

Õdö

õ-

adolescent, youth,

 

Ômödé

ô--

child

Ilê

Èwe

è-we

youth, young

 

 

 

folks, children,

Ìbêrê

 

 

childhood

Òpin

Ôkùnrin

ô-kùn-rin

man

Iwájú

Obìnrin

o-bìn-rin

woman

Êyìn (Êhìn)

Akô

a-

male

Iÿë

Abo

a-bo

female

Eré

-ì-õ-gbë-ni

ì--à-a-fin a-bi-- o-mi-dan a- --

gbó-ná tú- --

o--à-le- õ-ô--i-ÿë ô--õ-

ì--è-rè ì--hùn è-sì ò-

i-

ì--rê ò-pin i-- ê-yìn (ê-hìn) i-s³e³;

e-

father mother Mr.

Mrs?

Mrs

Miss

Miss?

hot (adj) cold (adj) lukewarm

host guest master apprentice servant

question answer reply top, hill, mountain ground

beginning end

front back work play

oókanléláàta

(Four short of seventy)

Page 66

Ojú Ìwé Kçrìndínláàádörin

 

 

 

Àkójô õrõ - Onírúurú

 

 

 

 

 

Vocabulary -

Miscellaneous

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Ààyè

à-à-

living

 

 

Ìdúpë

 

ì--

thanksgiving

 

Agbára

a-gbá-ra

power

 

 

Ìlànà

 

ì--

procedure

 

Àgbàrá

à-gbà-

torrent

 

 

Ilé-ìwòsàn

 

i--ì--sàn

hospital

 

Àgbáyé

à-gbá-

world

 

 

Ilê

 

i-

floor, ground

 

Àìmoye

à-ì-mo-ye

countless

 

 

Ìmõ

 

ì-

knowledge

 

Àkójôpõ

à---

collection

 

 

Ìmõràn

 

ì--ràn

advice

 

Àkókò

à--

time

 

 

Ìran

 

ì-ran

generations,

 

Àkökö

à--

first

 

 

 

 

 

sight

 

Àmì

à-

sign

 

 

Ìrókò

 

ì--

African teak

 

Àýfàní

à-ý--

benefit

 

 

 

 

 

tree

 

Àÿà

à-ÿà

habit, custom

 

 

Ìÿe

 

ì-ÿe

custom, habit

 

Àÿá

à-ÿá

hawk (bird)

 

 

Iÿë

 

i-ÿë

work

 

Àÿç

à-ÿç

order

 

 

Ìÿòro

 

ì--ro

difficulty

 

Àwòrán

à--rán

picture

 

 

Ìtúmõ

 

ì--

meaning

 

Àwõn

à-wõn

net

 

 

Ìyàtõ

 

ì--

difference

 

Àwôn

à-wôn

they

 

 

 

 

 

 

 

Àyà

à-

chest

 

 

Káàkiri

 

-à-ki-ri

everywhere

 

Aya

a-ya

wife

 

 

Kàwé

 

-

read

 

Àyè

à-

space

 

 

Kõwé

 

-

write

 

Ayé

a-

world

 

 

 

to learn,to

 

 

 

 

 

 

 

 

 

teach

 

Dára

-ra

good

 

 

 

to refuse

 

Dökítà

--

doctor

 

 

 

write

 

Dúpë

-

to thank

 

 

 

clean

 

 

 

 

 

 

 

to know

 

Êkö

ê-

lesson

 

 

 

to mould

 

Çgbë

ç-gbë

association

 

 

 

 

 

 

 

Êgbë

ê-gbë

side

 

 

Ojoojúmö

 

o-jo-o--

everyday

 

 

 

 

 

 

Ohùn

 

o-hùn

voice

 

Gëgë

-

accordingly

 

 

Olùdarí

 

o--da-

director

 

Gidigidi

gi-di-gi-di

very much

 

 

Ogunlögõ

 

o-gun--

very many

 

Gbìyànjú

gbì-yàn-

to try

 

 

Õrõ

 

õ-

word

 

 

 

 

 

 

Ôrõ

 

ô-

wealth

 

Ìdálê

ì--

a place abroad

 

 

Õnà

 

õ-

road

 

 

 

 

 

 

Ônà

 

ô-

art

 

 

 

 

 

 

pàtàkì

 

--

important

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 67

 

 

 

 

 

 

(Three short of seventy)

 

 

 

 

 

 

 

 

Ojú Ìwé Kçtàdínláàádörin

APPENDIX 1

Àwôn Ìdáhùn Õrõ Yoruba

Yoruba Word List Answers

Page 14

 

 

 

Page 17

 

 

Ajá

A-

Dog

 

 

Ìdí

Ì-

Reason

Àjà

À-

Attic

 

 

Ibí

I-

Place

Àgbà

À-gbà

Adult

 

 

Ibi

I-bi

Evil

Àpá

À-

Scar

 

 

Ìrì

Ì-

Dew

Àpà

À-

Prodigal

 

 

Ìgbì

Ì-gbì

Wave

Ara

A-ra

Body

 

 

Ìtí

Ì-

Beam

Àrà

À-rà,

Fashion

 

 

 

 

 

Ará

A-

Relation

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 15

 

 

 

 

Page 18

 

 

Èwe

È-we

Youth

 

 

Òwò

Ò-

Trade

Eré

E-

Play

 

 

Òkò

Ò-

Stone

Èrè

È-

Profit

 

 

Okó

O-

Penis

Ète

È-te

Intention

 

 

Òjó

Ò-

A name

Èdè

È-

Language

 

 

Ojo

O-jo

Coward

 

 

 

 

 

Òdo

Ò-do

Zero

 

 

 

 

 

Odó

O-

Mortar

 

 

 

 

 

Opó

O-

Widow

 

 

 

 

 

Òpò

Ò-

Bother

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 16

 

 

 

Page 19

 

 

Êjë

Ê-

Vow

 

 

Ôkõ

Ô-

Vehicle

Çsç

Ç-

Verse

 

 

Ôkô

Ô-

Husband

Êyç

Ê-

High esteem

 

 

Ôkö

Ô-

Hoe

 

 

 

 

 

Õkõ

Õ-

Spear

 

 

 

 

 

Õwõ

Õ-

Respect

 

 

 

 

 

Ôwõ

Ô-

Broom

 

 

 

 

 

Õwö

Õ-

Flock

Àkíyèsí: Àwôn õrõ mélòó kan ní ìtúmö tí ó ju õkan lô. Õkan péré ni a töka sí níbí.

Note: Some words have more than one meaning. Only one has been indicated here.

Àwôn Ìdáhùn Õrõ Yoruba

Yoruba Word List Answers

Page 20

Page 25

Kúkú

-

 

Rather

 

 

Ìlú,

Ì-

Town

Kúkù

-

 

A name

 

 

Ìlù

Ì-

Drum

Kújú,

-

 

Dull

 

 

Ìlà

Ì-

Line

Fùfú,

-

 

Cassava meal

 

 

Ilá

I-

Okro

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 22

 

 

 

 

 

Page 26

 

 

Àgbo

À-gbo

 

Concoction

 

 

Oyè

O-

Title

Agbo

A-gbo

 

Circle

 

 

Ôyë

Ô-

Harmattan

Àwo

À-wo

 

Plate

 

 

Owú

O-

Envy

Awo

A-wo

 

Cult

 

 

Òwu

Ò-wu

A town

Abë

A-

 

 

 

 

Orí

O-

Head

Apó

A-

 

Sheath

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 23

 

 

 

 

Page 27

 

 

Èní

È-

Today

 

 

Ôpë

Ô-

Gratitude

Ènì

È-nì

Over-measure

 

 

Õdê

Õ-

Dunce

Èjí

È-

Gap between

 

 

Ônà

Ô-

Art

teeth

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 24

 

 

 

 

 

Page 28

 

 

Çgba

Ç-gba

 

Whip

 

 

À--

À--

Turtle

Êpà

Ê-

 

Peanut

 

 

Õ--

Õ--

Toad

Ç

Ç-

 

Case

 

 

Ò--

Ò--

Incantation

 

 

 

 

 

 

Ò-do-do

Ò-do-do

Truth

Àkíyèsí: Àwôn õrõ mélòó kan ní ìtúmö tí ó ju õkan lô. Õkan péré ni a töka sí níbí. Note: Some words have more than one meaning. Only one has been indicated here.

Àwôn Ìdáhùn Õrõ Yoruba

Yoruba Word List Answers

Page 30

 

 

 

Page 37

 

 

Ôkàn

Ô-kàn

Heart

 

 

Òrí

Ò-

Head

Õsán

Õ-sán

Afternoon

 

 

Ète

È-te

Lip

Êsan

Ê-san

Revenge

 

 

Ìkà

Ì-

Finger

Çfõn

Ç-fõn

Elephant

 

 

Àpá

À-

Arm

Àgbôn

À-gbôn

Coconut

 

 

Àpà

À-

Prodigal

Agbõn

A-gbõn

Basket

 

 

Àgbôn

À-gbôn

Coconut

Àgbõn

À-gbõn

Chin

 

 

Agbön

A-gbön

Bee

Ôgbön

Ô-gbön

Wisdom

 

 

Õkan

Õ-kan

One

 

 

 

 

 

Ikún

I-kún

Stomach

 

 

 

 

 

Aya

A-ya

Chest

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 31

 

 

 

 

Page 40

 

 

Êyin

Ê-yin

You (plural)

 

 

Bàbà

-

Barley

Çyìn

Ç-yìn

Nut

 

 

Bàtá

-

Shoe

Êsìn

Ê-sìn

Religion

 

 

Òro¸bó

Ò-ro-¸-

Orange (fruit)

Êsín

Ê-sín

Shame

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Page 32

 

 

 

Page 41

 

 

Òkun,

Ò-kun,

Ocean

 

Roboto

Ro-bo-to

Round

Okun

O-kun

Strength

 

Rçpçtç

--

Flat

Çkún

Ç-kún

Cry

 

 

 

 

Êkùn

Ê-kùn

Fullness

 

 

 

 

Õrun

Õ-run

Heaven

 

 

 

 

Ogun

O-gun

War

 

 

 

 

Ògún

Ò-gún

god of iron

 

 

 

 

Ikún

I-kún

Phlegm

 

 

 

 

Ikun

I-kun

Abdomen

 

 

 

 

Àkíyèsí: Àwôn õrõ mélòó kan ní ìtúmö tí ó ju õkan lô. Õkan péré ni a töka sí níbí. Note: Some words have more than one meaning. Only one has been indicated here.

Preface to first Edition

Ní ayé òde òní, ogunlögõ àwôn ômô ìbílê Yorùbá ni ó di çni tí ó sô ìdálê di ilé yálà fún ìgbà díê, tàbí ní ìdúró pë títí. Nípa báyìí, wôn þ dara põ mö àwôn ìran mõlëbí bàbá þlá wôn àtijö, àwôn ìran Yorùbá ilê Bràsíìlì, Kúbà, Trinidáàdì àti Tòbágò, káàkiri ìlê Karíbíáànì àti Àkójôpõ Ilê Amëríkà àti gbogbo àwôn tí ó fön káàkiri àgbáyé.

Ó di õrànyàn fún wíwà láàyè ìÿe àti àÿà ìbílê láti ní àwôn ìwé, magasínìnnì àti oríÿìíríÿìí àwôn ñýkan ìmõ tí a fi kõýpútà ÿe ní àröwötó tí èdè, ìÿe àti àÿà ìbílê Yorùbá kò bá ní pare láàárín àwôn wõnyí àti ìran wôn. Irú àwôn ñýkan bàyìí ÿõwön púpõ ní löölöö yìí. Õpõlôpõ àwôn ìwé êkö èdè tì a þ mú wá láti ilé kìí wúlò púpõ fún iÿë yìí. L’önà kìn-ín-ní, a ÿe wôn fún êkö èdè ní ilê Yorùbá ni, à sì kô wön láti òkè dé ilê ní èdè náà ni. Ní õnà kejì êwê, àwôn gbòýgbò õrõ tí ó wà nínú wôn ÿe àjèjì sí çni tí ó þ dàgbà ní ìdálê.

Bí ó tilê jë pé ó ÿe pàtàkì láti fi ìÿe àti àÿà ìbílê hàn nínú àwôn ìwé yìí, tí ó sì jë pé ohun tí a þ lépa nìyìì, ó tö, ó sì yç kí a fi àwôn ñýkan tí ó jç mímõ fún akëkõö kún un láti fi fà wön möra, kí ìfë wôn sì dúró.

Púpõ nínú àwôn ìlú tí àwôn ômô Yorùbá põ sí ní ìlú òkèèrè ni ó þ dá ilé-ìwé sílê fún kíkö àwôn ômô wôn ní èdè ìbílê. Àwôn olùkö tí ó yõýda ara wôn fún iÿë yìí ÿùgbön tí kìí ÿe pé wôn kö èdè jinlê sì wà láàárín àwôn tí ó þ bójú tó irú àwôn ilé-ìwé bëê. Àwôn òbí tàbí aya àti ôkô pàápàá þ bá ara wôn ní ipò olùkö-èdè fún àwôn tí ó súnmö wôn, ÿgbön láì ní ñýkan èlò fún iÿë yìí, ó þ jë ìÿòro fún wôn. Ìwé yìí wà fún sísô èle yìí di êrõ. Êkö èdè Yorùbá wà nínú ètò êkö àwôn ilé-ìwé gíga mèlòó kan ní ìdálê báyìí. Àwôn ìwé tí ó wà fún êkö yìí lè ÿòro fún alákõöbêrê tí kò bìkítà fún gírámà þlá ní ìbêrê ÿùgbön tí ó kàn fëë mõn ön kô, mõn ön kà fún ìgbádùn lásán ni. Ìdí tí a fi ÿe àwön õwö ìwé yìí nìyìí. Ç máa gbádùn ìwé kíkö yin.

Preface to first Edition

In recent times an increasing number of Yorubas are taking up residence abroad either temporarily, but for extended periods of time, or permanently. In a way, they are joining the descendants of their forebear’s cousins of generations past, people of Yoruba heritage in Brazil, Cuba, Trinidad & Tobago, all over the Caribbean and the United States of America and indeed a great many others scattered worldwide.

In order to ensure the long term survival of the Yoruba culture in generations unborn, it is necessary for these groups to have at their disposal books, magazines, computer programs and other resources that will help them appreciate their roots. There is a dearth of such material at the present time. Many of the books available for language learning are imported and may not be particularly useful for this purpose. In the first place, the books are designed for use in Yoruba-land and as such are written entirely in Yoruba. Secondly the theme of the writings is usually not familiar to users growing up abroad. Whilst it is essential to convey aspects of Yoruba culture in the writings, and indeed this is the ultimate objective, it is essential to incorporate themes familiar to the reader to attract and sustain their interest.

Several communities abroad have established Yoruba schools to teach their children Yoruba language and culture. These schools are usually manned by volunteer teachers who are not necessarily trained experts. Parents and spouses also find themselves in the position of wanting to teach but with no resources. This book is designed to alleviate this problem. Yoruba language features in the curriculum of some academic centers abroad. The material available for these studies may be too academic for the average person whose immediate concern is not to master the intricacies of the grammar but to find a practical way to learn the language in a fun way. This is the purpose for which these series have been created. Enjoy your studies.

P

Ìdupë Pàtàkì

Special Acknowledgement

Mo dupe púpõ löwö Õjõgbön-àgbà Õmõwé Adébóyè Babalôlá tí wôn ÿe àyêwò àtêjáde kìnínní ìwé yìí tí wôn sì ÿe àtúnÿe àwôn àÿìÿe mi láìjáfara.

Õjõgbön Babalôlá jë ògbóýtagí onímõ-ìjìnlê Yorùbá. Olórí Çka Ìmõ Èdè àti Lítíréÿõ Áfríkà ní Yunifásítì Ìlú Èkó, Nàìjíríà ni wôn jë fún õpõlôpõ ôdún kí wôn tó fêhìntì nibi-iÿë.

A óò máa ríi yín bá o.

Õjõgbön Adébóyè Babalôlá di olóògbè ní ôjö kçêëdógún, oÿù kejìlá, ôdún 2008. Sùn re o, Bàbá.

I am indeed very grateful to Emeritus Professor Adeboye Babalola who, at short notice, reviewed the first edition of this book and corrected my mistakes.

Professor Babalola is a renowned Yoruba scholar who was for many years the head of Department of African Languages and Literatures, University of Lagos, Nigeria, prior to his retirement.

We are following your footsteps.

Professor Adeboye Babalola was deceased on December 15, 2008 at the age of 82. May his gentle soul rest in peace.

Báwo ni o ti rí ìwé yìí sí?

Kí ni àwôn ñýkan tí o fëë rí nínú àtúnÿe rê ní ôjö iwájú?

Kõwé sí wa.

What is your impression about this book?

What are the changes you would like to see in a future edition?

Write to us